Igbimo to n mojuto Eka Imunimofin ni Ijoba Ipinle Ondo je agbekale lati le yan awon adajo ati lati le ko awon adajo ati awon osise Eka Imunimofin ni Ijoba Ipinle Ondo ni ijanu. Alaga igbimo yii ni Adajo Agba ni Ijoba Ipinle. Awon omo Igbimo yooku ni- Adajo Agba Imunimofin ni Ipinle ati Komisona Komisona fun Idajo ati awon merin miiran, eyi ti Gomina Ipinle ba yan. Igbimo yii ni akowe eni to wa ni igbonnu eto igbimo.
O je idasile labe Ori kefa, Abala igba-din-meta (ipin kiini) ofin Orile-ede Naijiria ti 1979 pelu awon to ye ko je omo Igbimo, ojuse ati agbara Igbimo bi won se la a kale ni ipin keji abala keta ofin. Ojuse re jo ti afojusun ati iri Igbimo to n mojuto Osise Ijoba. Gege bi alakale Abala Igba-le-meji ati igba-le-merin ofin odun 1999, Igbimo to n mojuto Eka Imunimofin ni Ijoba Ipinle le se ofin tire. Ofin fi aaye gba ki Igbimo to n mojuto Eka Imunimofin ni Ijoba Ipinle gege bii Igbimo to n mojuto Osise Ijoba ati Igbimo to n mojuto Eto Idibo ma se gba itoni lati odo awon alase miiran tabi lodo eniyan kankan.
o da Igbimọ Iṣẹ Adajọ ti Ipinlẹ Ondo jẹ agbekalẹ nipasẹ Alakoso Alagbada ti akọkọ ti Ipinle, Oloye Micheal Adekunle Ajasin pẹlu Hon. Onidajọ Orojo gẹgẹbi Alaga Akọkọ rẹ. Ofin ti o ṣeto Igbimọ naa ni ikede ati wole si ofin ni ọjọ 14 Oṣu kejila ọdun 1979.
1. MR ADEGBEMIBO F.A. 1980 - 1984
2. MR ALONGE M.B 1985 - 1986
3. MR KUEWUMI H.O. 1986 - 1987
4. MR OSO E.J.O. 1987 - 1988
5. MR OBAREMO S.O. 1988 - 1993
6. MR OGUNLOLA I.B. 1993 - 1996
7. MR OLUBOLA M.O. 1996 - 2012
8. MR ENIKUOMEHIN A. 2012 - 2014
9. CHIEF AKINRINSOLA S.A. 2014 - 2017
10. CHIEF EGBUNU Z.P. JP 2017 - 2017