A da Eka Imunimofin ti Ijoba Ipinle Ondo sile lati ara Ijoba Iwo Oorun Naijiria ni ojo keta osu keji odun 1976. Eka Imunimofin ti Ijoba Ipinle Ondo bere pelu Ekun meata wonyi- Akure, Ondo ati Ado-Ekiti ati awon adajo marun-un wonyi ni ipile, Hon. Justice (Dr) Akinola Aguda, gege bi Adajo Agba, Hon. Justice C. Piper, Hon Justice O. Olatawura, Hon. Justice Olakunle Orojo, ati Hon. Justice M. E. Ogundare, to gbogbo won si ti di oloogbe bayii.
Ni odun 1976, won yan Hon Justice S. F. Adeloye gege bi adajo Ile-Ejo Giga Ipinle Ondo, eni ti o je Adajo Agba ti won o koko yan ni Ipinle Ondo.
Leyin to won da Ijoba Ipinle Ekiti sile no odun 1996, awon Ile-Ejo to wa ni ile Ekiti bi si abe Eka Imunimofin Ijoba Ipinle Ekiti ti awon Ile-Ejo to wa ni Ile Ondo si wa ni abe Ijoba Ipinle Ondo. Lati ori ipile to dara yii si ni awon Ile Ejo to wa ni Ijoba Ipinle Ondo ti ni Ekun mewaa wonyi: Akure, Owo, Ikare, Ondo, Okitipupa, Ifon, Oka, Idanre, Igbara-Oke ati Ekun Ore.
Awon Agbejoro mokanlelaaadota lo n jokoo ni Ekun Igbejo mejilelogun kaakiri Ijoba Ipinle ati Awon Ayalo Igbimo Igbejomewaa kaakiri Ijoba Ipinle eyi to je pea won Amunimofin to yanranti lo n dari won.
Ni odun 2006 ni ilkepa abal ofin okoodinlooodunrun ofin orile ede Naijiria (pelu atunse). Ile Igbimo Asofin Ijoba Ipinle Ondo se amulo Ofin to da Ile Ejo Alabode Ko-te-mi-lorun sile.
Sugbon, nitori igbese to wa ninu isodofin pelu ibuwolu Gomina ni ojo kejila osu karun-un odun 2007, Ile Ejo yii ko bere titi di osu keta odun 2011 nigba ti Hon. Justice Olasehinde Kumuyi, Adajo Agba Ijoba Ipinle Ondo, pelu Igbimo to n mojuto Eka Imunimofin yan Omoobabinrin Eunice Aderonke Alade gege bi Akowe Agba ati Oloye Doubra gege bi Igba keji Akowe Agba lati bere Ile Ejo Alabode Ko-te-mi-lorun ni Ijoba Ipinle Ondo. Awon Adari to wa ni ipile yii beere fun awon osise ni Ile Ejo Giga, won sib ere ise lati inu ayalo ofiisi meta ni Gbongan Igbimo to n mojuto Eka Imunimofin to wa ni Oke Eda, Akure.
Ni odun 2013, won se ifilole Ile Ejo Alabode Ko-te-mi-lorun pelu Hon. Justice F. O. Aguda-Taiwo gege bi Alakooso. Awon Adajo meta miiran ni: Hon. Justice E. A. Alade, C. T. Adesola ati M. A. Owoyemi. Ile Ejo yii di Ile Ejo gidi nigba ti Comrade Governor, Dr. Olusegun Mimiko yan Alakooso ati awon adajo meta miiran yiini ojo kerinla osu keji ni odun 2013.
Hon. Justice Folashade Oluwatoyin Aguda-Taiwo ni Alakooso ipile. Awon adajo yooku ni- Hon. Justice Eunice Aderonke Alade (Pioneer Chief Registrar), Hon. Justice Adesola Titilayo Ikpatt, Hon. Justice Akinfemi Owoyemi; lati igba yii ni Ile Ejo yii si ti n se ojuse re lati ilepa imudagbasoke awujo n te siwaju nipa fifi idi eto awon eniyan awujo mule.
Ibi ti Ile Ejo yii wa lowolowo bayii ni Gbongan Igbimo to n mojuto Eka Imunimofin to wa ni Oke Eda, Akure, Ipinle Ondo.
Awon Adajo Agba ni ile ejo giga Ijoba Ipinle Ondo:
1 Late Hon. Justice (Dr) Timothy Akinola Aguda (1976-1978)
2. Late Hon. Justice (Dr) Olakunle Orojo (1978 1984)
3. Late Hon. Justice Solomon Folarin Adeloye (1984-1996)
4. Hon. Justice Sidney A. Afonja (1996- 1998)
5. Late Hon. Justice Ayoola O. Ogunleye (1998 2000)
6. Late Hon. Justice Adetunji Adetosoye (2001)
7. Late Hon. Justice J. O. Falodun (2001-2003)
8. Late Hon. Justice (Dr) Gladys Olubunmi Olateru-Olagbegi, OFR - (2003 - 2010)
9. Hon. Justice Olasehinde Kumuyi (2010 to 2017)
10. Hon. Justice Olanrewaju Olutoyin Akeredolu (2017 to 2021)
11. Hon. Justice Williams Akintoroye (2021 to 2022)
12. Hon. Justice Ayedun Odusola (2022 to present)
Awon Adajo Agba ni ile ejo asa ni Ijoba Ipinle Ondo:
1. Hon. Justice Folashade Oluwatoyin Aguda-Taiwo (2013-2019)
2. Hon. Justice E.A Alade (2019 - Present)