Nipa Wa

EKA IMUNIMOFIN NI IJOBA IPINLE ONDO

Asamo

Eka Imunimofin ni Ijoba Ipinle Ondo wa ni igbonnu isakoso awon eniyan awujo, iwa odaran, ati ohun to ba je mo idile ni ibamu pelu alakale ofun Ijoba Apapo Orileede Naijiria. Bakan naa, o ni ase ju lo ati ojuse fun fifun ofin ni itumo ati sise amulo ofin ijoba ipinle. Awon to wa labe Eka Imunimofin ni Ijoba Ipinle Ondo niwonyi-Ile-Ejo giga ju lo, Ile-Ejo Alabode Ko-te-mi-lorun, Multidoor Courthouse, Awon Ile Agbejoro Alabode, ati awon Ayalo Igbimo Agbejoro. Adajo Agba ni olori eka Imunimofin, eyi ti o je pe ojuse re ni lati se idari ati isakoso igbejo ni kootu ati ipade awon Ayalo Agbejoro ati ise to ba je mo awon awon amunimofin ni Ijoba Ipinle.

Eka Imunimofin ni Ijoba Ipinle Ondo durosinsin ninu ilepa re lati mu idagbasoke ba eto omoniyan nipase amulo imo ero igbalode ati mimu idagbasoke ba ohun gbogbo to ba je mo igbejo fun awon eniyan Ijoba Ipinle Ondo.

O je ilepa awon Amunimofin lati mu idagbasoke ba sise eto fun awon eniyan nipase imo ero.

Ilepa Wa

" Eto fun gbogbo eniyan: Ni abe isamulo Ofin ati abadofin, eyi ti awon oloooto eniyan lokunrin ati lobinrin ti won ti fi ara won jin fun otito, iwa omoluabi, isedeede, igboya ati iserere awujo lapapo.